请输入您要查询的单词:

 

单词 ọrọ-iṣe
释义

ọrọ-iṣe

Yoruba

Alternative forms

  • IS (abbreviation)
  • ọ̀rọ̀ ìṣe

Etymology

From ọ̀rọ̀ (word) + ìṣe (action), literally action word.

Pronunciation

  • IPA(key): /ɔ̀.ɾɔ̀.ì.ʃē/

Verb

ọ̀rọ̀-ìṣe

  1. verb
    Kí ni ìtumọ̀ ọ̀rọ̀-ìṣe èdè Gẹ̀ẹ́sí "to meet"?
    What is the meaning of the English verb, "to meet"?
    • 2015 April 27, L.O. Adéwọlé, “Gírámà Gẹ̀ẹ́sì fún Àwọn Alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ (English Grammar for Beginners) - Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ Kejì (Second Lecture)”, in Yoruba for Academic Purpose:
      Oriṣìí Ọ̀rọ̀-ìṣe (Verb Types)
      Oríṣìí ọ̀rọ̀-ìṣe (verb) mẹ́ta ni ó wà. Àwọn náà ni aláìgbàbọ̀ (intransitive), asopọ̀ (linking) àti agbàbọ̀ (transitive).
      Verb Types
      There are three types of verbs. They are intransitive verbs, linking verbs, and transitive verbs.
    • ?, “Orúkọ Ọlọ́run Nínú Ìwé Mímọ́ Lédè Hébérù”, in ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower:
      Inú ọ̀rọ̀ ìṣe èdè Hébérù tó túmọ̀ sí “láti di” ni orúkọ náà, Jèhófà ti wá.
      The name Jehovah comes from a Hebrew verb that means “to become.”

Hyponyms

  • agbẹ̀yìn ọ̀rọ̀-ìṣe (post verb)
  • aṣáájú ọ̀rọ̀-ìṣe (preverb)
  • ọ̀rọ̀-ìṣe abáṣelọ (action verb)
  • ọ̀rọ̀-ìṣe abọ́dé (simple verb)
  • ọ̀rọ̀-ìṣe agbàbọ̀ (symmetrical verb)
  • ọ̀rọ̀-ìṣe àkànmórúkọ (compound verb)
  • ọ̀rọ̀-ìṣe aláìbáṣelọ (stative verb)
  • ọ̀rọ̀-ìṣe aláìgbàbọ̀ (intransitive verb)
  • ọ̀rọ̀-ìṣe alápèpadà (echoing verb)
  • ọ̀rọ̀-ìṣe àrànmásọdorúkọ (nominal-assimilating or complex verb)
  • ọ̀rọ̀-ìṣe àsínpọ̀ (serial verbs)
  • ọ̀rọ̀-ìṣe asolùwàdàbọ̀ (symmetrical verb)
  • ọ̀rọ̀-ìṣe aṣàpèjúwe (descriptive verb)
  • ọ̀rọ̀-ìṣe aṣàpọ́nlé (modifying verb)
  • ọ̀rọ̀-ìṣe aṣèròyìn (report verb)
  • ọ̀rọ̀-ìṣe aṣẹ̀dá-àpèjúwe (adjectivizable verb)
  • ọ̀rọ̀-ìṣe aṣẹpọ́n (modifying verb)
  • ọ̀rọ̀-ìṣe aṣẹ̀yán (modifying verb in grammar)
  • ọ̀rọ̀-ìṣe aṣokùn-ùnfà (causative verb)
  • ọ̀rọ̀-ìṣe ayẹ̀rún (particle-selecting verb)
  • ọ̀rọ̀-ìṣe ẹlẹ́là (splitting verb)
  • ọ̀rọ̀-ìṣe ìmọ-nǹkan (cognition verb)
  • ọ̀rọ̀-ìṣe kíkún (full verb)
  • ọ̀rọ̀-ìṣe oníbọ̀ (complex verb)
  • ọ̀rọ̀-ìṣe oníbọ̀ (complex verb)
  • ọ̀rọ̀-ìṣe ọ̀bọ̀rọ́ (infinitive verb)
  • ọ̀rọ̀-àfetíyá (ear-loan)
  • ọ̀rọ̀-áfojúyá (eye-loan)
  • ọ̀rọ̀-àkànlò (idiom)
  • ọ̀rọ̀-anítumọ̀-àdámọ́ (lexis, content word)
  • ọ̀rọ̀-àpèjúwe (adjective)
  • ọ̀rọ̀-àpọ́nlé (adverb)
  • ọ̀rọ̀-arọ́pò-orúkọ (pronoun)
  • ọ̀rọ̀-asopọ̀ (conjunction)
  • ọ̀rọ̀-atọ́kùn (preposition)
  • ọ̀rọ̀-àyálò (loanword)
  • ọ̀rọ̀-èdè (corpus, the words of a language)
  • ọ̀rọ̀-ìró-ìtumọ̀ (ideophone)
  • ọ̀rọ̀-ìrótumọ̀ (ideophone)
  • ọ̀rọ̀-orúkọ (noun)
  • ọ̀rọ̀-ọgbọ́n (phrase)

References

  • Awobuluyi, O. (1990) Yoruba Metalanguage (Ede-Iperi Yoruba) Vol. II (A Glossary of English-Yoruba Technical Terms in Language, Literature and Methodology), Ibadan: University Press Ltd.
  • Awoyale, Yiwola (December 19, 2008) Global Yoruba Lexical Database v. 1.0, volume LDC2008L03, Philadelphia: Linguistic Data Consortium, →ISBN
  • Nigerian Educational Research and Development Council (1992) Quadrilingual Glossary of Legislative Terms (English-Hausa-Igbo-Yoruba), Lagos: Federal Cabinet Office and Nigerian Educational Research and Development Council
随便看

 

国际大辞典收录了7408809条英语、德语、日语等多语种在线翻译词条,基本涵盖了全部常用单词及词组的翻译及用法,是外语学习的有利工具。

 

Copyright © 2004-2023 idict.net All Rights Reserved
京ICP备2021023879号 更新时间:2024/7/13 11:07:31