ẹni
Yoruba
Alternative forms
- ọni
- ọnẹ
Etymology
Proposed to have derived from Proto-Yoruboid *ɔ-nɪ̃
Pronunciation
- IPA(key): /ɛ̄.nĩ̄/
Noun
ẹni
- person, one
Derived terms
- ẹlẹ́ni
- ẹlòmíì
- ẹni a fẹ́ la mọ̀
- ẹnìkan (“a person”)
- ẹnikẹ́ni (“anyone”)
- ẹni tí ò gbọ́n lààwẹ̀ ń gbò
- ẹni tí ò lówó á léèyàn
- mọni (“to know a person”)
- Ọlọ́run ẹlẹ́ni mẹ́ta (“triune god”)