meriiiri
Yoruba
Alternative forms
- mérìíìírí, méríyìírí
Etymology
From the phrase méè rí ìyí rí (“I have not seen this before”).
Pronunciation
- IPA(key): /mé.ꜜɾíꜜí.ɾí/
Noun
méríìírí
- something unusual; strange
- 2022, “Ìjẹ́wọ́ Ìnàkí Shìnágawà Kan”, in Olongo Africa:
- Àbí, pípín ọtí bíà àti títàkurọ̀sọ pẹ̀lú ìnàkí ṣá jẹ́ oun méríìírí.
- I mean, sharing a beer and chatting with a monkey was a pretty unusual experience in and of itself.
-
Derived terms
- ìwé ìtàn-àròsọ méríìírí (“genre of fantasy novel”)